Submit Lyrics to wikilyrics


Baba, a tun pade l’oko Jesu Yoruba Hymn

Share

 Baba, a tun pade l’oko Jesu

A si wa teriba lab’ese Re

A tun fe gb‘ohun wa soke si O

Lati Wa anu, lati korin ‘yin.

Ayin O fun itoju ‘gbagbogbo,

Ojojumo l‘ao ma rohin ‘sc re;

Wiwa laye wa, anu Re ha ko?

Apa Re ki 0 fi ngba ni mera?

O se! Ako ye fun ife nla Re,

A sako kuro lodo Re poju;

Sugbon kikankikan ni O si np

Nje a de, a pada wa ‘le, Baba.

Nipa oko t‘0 bor’ohun gbogbo

Nipa ife t’o ta ‘fe gbogbo yo,

Nipa eje ti a ta fun ese,

Silekun anu si gbani si ‘le.

   

Amin.


Note: Please support wikilyrics by Sharing or dropping a comment here. Also, You can submit song lyrics, poem or anthem here and reach thousands of Audience!
VIEW:  Kirk Franklin - Melodies From Heaven Lyrics