Submit Lyrics to wikilyrics


CACGHB Yoruba Hymn 16 Baba, a sope ‘toju Re,

Share

1. Baba, a sope ‘toju Re,

   T’o f’alafia kun ‘le wa;

   Odo Re ni won ti san wa

   Owo Re l’o si ngbe won ro

2. Olorun, t’o ye k’a ma yin,

   L’a nkepe ninu ile wa;

   Oluwa orun, ti ko ko

   Lati ma gbe ile aye.

3. Jek’olukuluku ‘dile

   Ma kepe O tosan-toru;

   K’a ko omo at’ om’odo

   L’ofin at’ore-ofe Re.

4. Beni k’iran ti mbo ma so

   T’ola ooko Re t’o logo,

   Titi gbogbo wa y’o fi lo

   Dapo mo idile t’orun

AMIN


Note: Please support wikilyrics by Sharing or dropping a comment here. Also, You can submit song lyrics, poem or anthem here and reach thousands of Audience!
VIEW:  CACGHB Yoruba Hymn 24 L'oju ale 'gba't orun wo