Submit Lyrics to wikilyrics


CACGHB Yoruba Hymn 18 Lojojumo la ngbe O ga

Share

1. L’ojojumo l’a ngbe O ga

   Nigbati ile ba mo,

   T’a ba kunle lati yin O

   Fun anu ti owuro

2. L’ojojumo l’angbe O ga

   Pel’ orin n’ile-eko,

   L’ojojumo, pelu iyin,

   L’a nse ise wa gbogbo.

3. L’ojojumo l’a ngbe O ga

   Ninu orin k’a to sun

   Awon angel’ gbo, won si nso

   Awon aguntan Kristi

4. L’ojojumo l’a ngbe O ga

   Ki se ni iyin lasan;

   Otito ati igboran

   Nf’ogo Re han ninu wa.

5. L’ojojumo l’a ngbe O ga

   Gba t’a ngbiyanju fun krist’

   Lati ma farada iya

VIEW:  CACGHB Yoruba Hymn: 9 Jesu, Orun ododo

   K’a pa ese run n’nu wa.

6. L’ojojumo l’a ngbe O ga

   Tit’ ojo wa y’o fi pin

   Tao simi n’nu lala gbogbo

   L’alafia d’ojo Re

AMIN


Note: Please support wikilyrics by Sharing or dropping a comment here. Also, You can submit song lyrics, poem or anthem here and reach thousands of Audience!