Submit Lyrics to wikilyrics


CACGHB Yoruba Hymn 25 Baba, a tun pade l’oko Jesu

Share

1. Baba, a tun pade l’oko Jesu,

   A si wa teriba lab’ese Re,

   A tun fe gb’ohun wa s’oke si O

   Lati wa anu, lati korin ‘yin

2. A yin O fun itoju ‘gba gbogbo

   Ojojumo l’a o ma rohin ‘se Re,

   Wiwa laye wa, anu Re ha ko

   Apa Re ki O fi ngba ‘ni mora.

3. O se! A ko ye fun ife nla Re,

   A sako kuro lodo Re poju,

   Sugbon kikan kikan ni o si npe

   Nje a de a pada wa ‘le Baba

4. Nipa ooko t’o b’or’ ohun gbogbo

   Nipa ife t’o ta ‘fe gbogbo yo

VIEW:  CACGHB Yoruba Hymn 3: Ji Okan Mi, Ba Orun Ji

   Nipa eje ti a ta fun ese,

   Silekun anu, si gba ‘ni s’ile

AMIN 


Note: Please support wikilyrics by Sharing or dropping a comment here. Also, You can submit song lyrics, poem or anthem here and reach thousands of Audience!