Submit Lyrics to wikilyrics


Chigozie Wisdom – Ese Gan Ni

Share

C’mon Everybody

Let’s enter into His gates with Thanksgiving

And into His courts with Praise

Join me

C’mon

Balalolalolalelo

You do well oh

You take care of me

Mo m’ore

Uhuhuhuhuh, You do well oh

You do well oh

You take care of me

Mo m’ore

A dúpẹ’ bàbá fún ore ńlá rẹ

Àwa dúpẹ’ bàbá fún ore àánú rẹ

Ìgbà t’aye yomi

Ẹyin l’àbò mí

Ìgbà t’aye kọ’ mí

Ẹyin mo sá tọ’

Jésù mo m’ore

Ẹku’ ìtọ’jú mí

Ẹ ṣé gan ni

Ẹku’ ìtọ’jú mí

Mo m’ore

Ẹku’ ìtọ’jú mí

Ẹ ṣe gaani

Ẹku’ ìtọ’jú mí

Mo m’ore

Mele gbàgbé ore rẹ láyé mí

VIEW:  Kirk Franklin - Riverside Lyrics

Ẹ ṣé gaani

Ẹku’ itọju mí

Mo m’ore

Mele sàì dúpẹ’ lójojúmọ’ oo

Ẹ ṣé gaani

Ẹku’ ìtọ’jú mi

Mom’ore

Modupe bàbá oo

Fún ore ńlá rẹ

Ògbénúadélébọ’ ṣògo

Mo wá júbà lọdọ rẹ

B’ọ’dún ṣe ń b’ọ’dún láyé oo

Bẹẹni ore rẹ láyé mí pọ’si

Gbèsè ọpẹ mi pọ sugbọn

Ngo ṣe wọn tí mo léṣe

Jésù mo m’ore

Ẹkú ìtọ’jú mí

Ẹ ṣe gaani

Ẹkú ìtọ’jú mí

Mom’ore

Orísun ayọ’ mí mo júbà lọ’dọ’ rẹ

Ẹ ṣe gaani

Ẹkú ìtọ’jú mí

Mom’ore

Àti ní lẹ’yìn kojú máa tí ni

Ẹ ṣe gaani (Baba Mi)

Ẹkú ìtọ’jú mí

Mom’ore

Olùtọ́jú ènìyàn mo yín ọ lógo

VIEW:  Amelia Moore – moves Lyrics

Ẹ ṣe gaani (Awimayehun)

Ẹkú ìtọ’jú mí

Mom’ore

Mo Wa Fope fun bàbá o eeeeee.

Mma Mma Gi Ejuwom obi le

Ngozi gi o ne mem obi nsori nsori

Ekele oma, ottuto oma, ojija mma dirigi

Jesus anama si gi dalu o

Dalu Dalu

Onye ne me mma

Adim grateful

Sia Dalu chukwu Mee

Dalu Dalu

Onye ne me mma

Adim grateful

Eyele ‘abasi Agwalamo

Agwalamo

Sia fọn ká là mi

Sọ sọ

Sia fọn mu teghetewon teghe

Agwalamo

Sia fọn ká má mi

Sọ sọ

Ubangiji Mugode oo

Mugode o

Le ga du má yin

Mugode

Domi alerika soa kalemu

Mugode o

Le ga du má yin

Mugode

Ngode

VIEW:  Midnight Oil – Undercover Lyrics

Emabamiki baba oo, babaa mi oo

Ẹ ṣe gaani (Baba Mi)

Ẹkú ìtọ’jú mí

Mom’ore

Come follow me praise and thank him for holy blessings

You do well oo

You take care of me

Momoreeeeee

Ooohh ooohh oohhh oohhh yeeeehh


Note: Please support wikilyrics by Sharing or dropping a comment here. Also, You can submit song lyrics, poem or anthem here and reach thousands of Audience!