Submit Lyrics to wikilyrics

Ire Iran Lyrics by Adeyinka Alaseyori


 Ire Iran Lyrics by Adeyinka Alaseyori

Awon kan ku

laiisi imuse ileri

Olorun mi o fe

Awon kan feti gbo ileri titi kose

Sugbon ko pada se olorun

Ileri ti mogbo ninu bibeli

ateyi ti mo la loju ala

eyi ti mo ri ninu iran

ati isotele

Ire ire ire iran mi o tete se

Lori mi tete se maje nku kogo te de o

Ire iran o iran ire jo tete se mo mi lara o

Ire iran o iran ire jo tete se

Pataki pataki ni wipe imuse ileri

Akai moye ileri lati feti gbo ti o ba imuse pade o


Ida duro ileri idaduro ala tabi iran

Ole mu komo ologo ma rare o

Akoko imuse ileri o to

Ire iran se momi lara o

Gbogbo idile lo ni ire iran ati ibi iran

ei ati se tojewipe egun iran lo n tele opolopo kiri

Ire iran mi da o

akoko imuse mi ti de

Olohun wo lo ma ndahun adura o

Imuse ileri mi da o

Melo nigba to ti gbo poma travel owo local flight ri

ire iran Video


Note: Please support wikilyrics by Sharing or dropping a comment here. Also, You can submit song lyrics, poem or anthem here and reach thousands of Audience!
VIEW:  Artikal Sound System – Spiritual Broadcaster Lyrics