Submit Lyrics to wikilyrics


Iru Iriri Lyrics – Mr Gbera ft. Adeyinka Alaseyori Download

Share

 

Mr Gbera – Iru Iriri ft. Adeyinka Alaseyori Download Mp3 Lyrics

Download Audio

Ohun gbogbo to jababara fun won

sebohun lofi sara fun wo

Ohun toje ipalara fun won

ara irelofi jasi femi

tori moranugba ni

Ohun to lakoja to fa eri

lofa iku opolopo

oje dupe

Ona to hun lo to nmu onje wale

lomu opo lo orun oje dupe

Ona ofun re oda ona iku

oje dupe

Omo tori gbedani ohun logba emi opolopo oje dupe

Iru iriri ti mori gba la won kori

VIEW:  WurlD – LET YOU DOWN Lyrics

Sugbon anu ti morigba woko ri gba

Iru iriri ti mori gba la won kori

Sugbon anu ti morigba woko ri gba

Orisirisi iriri lohun sele

Aimoye nkan ta ogbori losele

Gbogbo orile ede ohun be ni titi

Iru iriri ti mori gba la won kori

Sugbon anu ti morigba woko ri gba


Note: Please support wikilyrics by Sharing or dropping a comment here. Also, You can submit song lyrics, poem or anthem here and reach thousands of Audience!