Submit Lyrics to wikilyrics


L’oju ale, ‘gbat ‘orun wo Yoruba Hymn

Share

 L’oju ale, ‘gbat ‘orun wo,

Won gbe abirun w’odo Re;

Onirum ni aisan won,

Sugbon won fayo lo ‘Ie won

Jesu a de I‘ojo ale yi,

A sunmo, t’awa t`arun wa,

Bi a ko tile le ri O,

Sugbon a mo p’O sunmo wa.

Olugbala, wo osi wa;

Omi ko san, mi banuje,

Omi ko ni ife si O,

Ife elomi si tutu.

Omi mo pe, l.sa.n l’aye

Beni won K0 faye sile,

Omi l’ore tfko se‘re,


Beni won ko ii O sore.

Ko s’okan ninu wa t’o pe,

Gbogbo WI’ il ni elese;

Awon t’o ii min O toto,

Mo ara Won ni alaipe.

VIEW:  Sinach - Peace In The Storm (lyrics)

Sugbon Jesu Olugbala

Eni bi awa n’lwo ‘se,

‘Wo ti ri ‘dnnwo bi awa

‘Wo si ti mo ailera wa.

Agbar’ owo Re wa sibe

Ore Re si li agbara

Gbo adurl ale wa yi,

Ni anu, wo gbogbo wa san.

       

Amin.


Note: Please support wikilyrics by Sharing or dropping a comment here. Also, You can submit song lyrics, poem or anthem here and reach thousands of Audience!