Submit Lyrics to wikilyrics

Lyrics: Olori Kokoro Baba Si Fun mi OLUBUKOLA BEKES

Share

Lyrics: Olori Kokoro Baba Si Fun mi OLUBUKOLA BEKES

Lyrics: Olori Kokoro Baba Si Fun mi OLUBUKOLA BEKES English Translation

Olori kọkọrọ, Baba, fi fun mi. (= Father, give me

The master key)

Kọkọrọ to n ṣsilẹkun ire. (= the key that opens the door of good

Things) Gbogbo ọna ta ti ti mọ mi. (=All the doors barred

Against me)

Ba mi ṣsi wọn k’ogo rẹ yọ l’aye mi. (=Help me

Open them so that your glory will show in my life.)

SOLO: Emi ti gbe oju mi sori oke wọnni. (=I have lifted up my

Eyes to the hills)

Nibi ti iranlọwọ mi wa. (=where my help is)

Baba, tete dide iranlọwọ fun mi. (=Father, quickly rise to my help)

Ko gbe mi de ibi to ga j’ọta mi lọ (=Place me far above my enemies).

(CHORUS)

CALL: Mo ti gba a (=I have collected it)

RESPONSE: Kọkọrọ mi (=my key)

VIEW:  Lil Tjay - Part of the Plan Lyrics

CALL: Ta lo fi fun ọ? (=Who gave it to you?)

RESPONSE: Jesu lo fi fun mi. (Jesus gave it to me)

CALL: Mo ti d’oloriire o. (=I have become a lucky person)

RESPONSE: Mo ti soriire. (=I have become lucky)

CALL: Lorukọ Jesu (In Jesus’ name)

RESPONSE: Ire mi de (My blessing has come)

CALL: Orukọ t’iku gbọ to sa wọ’gbo lọ (=The name which Death heard

And ran into the forest)

RESPONSE: Aye, ẹ ba mi yọ (Everybody, rejoice with me)

CALL: Mo ti d’oloriire (I have become a lucky person)

RESPONSE: Ire mi de. Aye, ẹ ba mi yọ (My blessing has come.

Everybody, rejoice with me).

CALL: Ire ọmọ, ire alaafia, o ti wọle mi wa. (The blessings of

Children and good health have come to me)

RESPONSE: Ire mi de. Aye, ẹ ba mi yọ (My blessing has come.

Everybody, rejoice with me).

CALL: Mo ti kuro ni tẹnanti. Mo ti di landlord. (I’m no longer a

VIEW:  Nas - Wave Gods Lyrics

Tenant. I have become a landlord)

RESPONSE: Ire mi de. Aye, ẹ ba mi yọ (My blessing has come.

Everybody, rejoice with me).

CALL: Ẹ ba mi dupẹ. Mo ti ra mọto tuntun. (Rejoice with me. I have

Bought a new vehicle)

RESPONSE: Ire mi de. Aye, ẹ ba mi yọ (My blessing has come.

Everybody, rejoice with me).

ALL: Ariwo ayọ la n fẹ. Ariwo ayọ nile wa. (We want shouts of joy,

Shouts of joy in our homes)

CALL: Baba ibeji, ẹ ku ewu ọmọ. (Father of twins, congrats)

RESPONSE: Ariwo ayọ nile wa. (Shouts of joy in our homes)

CALL: Ọkọ ati iyawo, ẹ ku oriire. (Groom and bride, congrats)

RESPONSE: Ariwo ayọ nile wa. (Shouts of joy in our homes)

CALL: Visa America rẹ ti de. (Your American visa has come through)

RESPONSE: Ariwo ayọ nile wa. (Shouts of joy in our homes)

CALL: Lorukọ Jesu (In Jesus’ name)

RESPONSE: Ire mi de. Aye, ẹ ba mi yọ (My blessing has come.

VIEW:  Crowbar – Denial of the Truth Lyrics

Everybody, rejoice with me).

CALL: Ẹ ki mi ku oriire. O ti de [ Congratulate me. It has

Come]

RESPONSE: Ire mi de. Aye, ẹ ba mi yọ (My blessing has come.

Everybody, rejoice with me).

CALL: Ẹ wo kọkọrọ moto ti mo sẹsẹ gbe de lati London. (See the keys

Of the vehicle I just brought in from London)

RESPONSE: Ire mi de. Aye, ẹ ba mi yọ (My blessing has come.

Everybody, rejoice with me).

ALL: Ariwo ayọ la n fẹ. Ariwo ayọ nile wa. (We want shouts of joy,

Shouts of joy in our homes)

Note: Please support wikilyrics by Sharing or dropping a comment here. Also, You can submit song lyrics, poem or anthem here and reach thousands of Audience!