Submit Lyrics to wikilyrics


Olorun To Tobi Lyrics by Mosun Olaitan

Share

Download Audio.mp3

Mosun Olaitan – Olorun To Tobi Lyrics

Baba toju babanla wa

O gbo orun ro kofi tenikan se

Arabata ribiti Arugbo igba ni

Baba toju babanla wa

Baba tofi idi aye sole

Ogbo orun ro kofi tenikan se

Arabata ribiti Arugbo igba ni

Baba toju babanla wa lo

Olorun to Tobi

Olorun Baba Agba

Aye o gba o

O f ‘orun se Ibugbe

Aye o gba o

O f ‘orun se Ibujuko

Olorun to Tobi

Olorun Baba Agba…

Olorun to Tobi

Olorun Baba Agba

Aye o gba o

O f ‘orun se Ibugbe

Aye o gba o

O f ‘orun se Ibujuko

VIEW:  Bruno Mars - Liquor Store Blue Lyrics

Olorun to Tobi

Olorun Baba Agba… 

 Aweda Ameda

Araye rorun

Okin se eniyan rara

Emini emini ti nje emini

Atobajaye

Aye o gba o

Alade ogo

Ohh Jehovah Elohim

Oba tin be nibi gbogbo

nigba gbogbo lekan soso

Obiri ki aji pojo iku da

Olorun to Tobi

Olorun Baba Agba

Aye o gba o

O f ‘orun se Ibugbe

Aye o gba o

O f ‘orun se Ibujuko

Olorun to Tobi

Olorun Baba Agba… 

Mosun Olaitan – Olorun To Tobi Lyrics

Eleda olowo gbogbo ti nyomore lofin aye

Adagun fologun

Okan soso araba ti n migbo Kiji kiji

Alapa kabi kabi

Oloju je nba oso

baba mi tolohun arare

tobi rare to tun sorare loruko

VIEW:  CAC GHB 26 : LEAD KINDLY LIGHT AMID THE ENCIRCLING GLOOM

Erujeje erujej Oko Pharao

Mosun m oba nigba egbefa mojin

na soba nigba egbeje

Eni roba fin lobanpa

Olorun to Tobi

Olorun Baba Agba

Aye o gba o

O f ‘orun se Ibugbe

Aye o gba o

O f ‘orun se Ibujuko

Olorun to Tobi

Olorun Baba Agba… 


Note: Please support wikilyrics by Sharing or dropping a comment here. Also, You can submit song lyrics, poem or anthem here and reach thousands of Audience!