Submit Lyrics to wikilyrics

Tope Alabi oba aseda


A toto n to Olodumare, Olorun ogo,

Iba Re, Iba o, Akoda aye, Iwo nikan lo to, iba!

A de′da, a m’eda Oba

Alamo to mo ′ponri eda o

Akoko orun on aye

Opo kan a gbamu aye o

Ogo ni mo wa yin o o Oba

Kabiyesi Re, Olorun toto

Ogo, yeeee, ogo

Akoko ade Iwo loba

Omimi aye ti o le mi lailai o

Olu inu awon orun

Asaya apesin asako

Iwo to tobi ju o lorun

O f’aye s’apoti itise lasan

Ogo, yeeee, ogo

Ogo ye o, yeeeee ogo

Olorun agbaye, mo f′ogo fun O ooo

Iwo loba Aseda, mo f′ogo fun O

Iwo lajulo ti o see julo, mo f’ogo fun O Baba

Iwo loba Aseda, mo f′ogo fun O

Atetekose Adiitu Oro, mo f’ogo fun O Baba

Iwo loba Aseda, mo f′ogo fun O

Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O

— Tope Alabi

Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O

Iwo ni ‘gunwa ogo ti o lafiwe, mo f′ogo fun O Oba nla

Iwo loba Aseda, mo f′ogo fun O

Awari Re aimo ni f’aye at′orun

Ipa o to ju gbogbo ipa lo

Angeli o le s’akawe ogo Re

Didan ninu ewa at′orun d’orun

O da′ye k’ohunkohun to d’aye

Akoko k′angeli orun to wa

Iwo to n s′ohun to tobi ju awari lo

Owo ogo to f’ara s′ohun gbogbo logo

Ogo yeeeee ogo

Iba o, yeeeee iba o

Iba Re Olorun o, Oba ayeraye e

Kabiyesi Re o, Iwo nikan lola ododo to si

Mo wa juba Re o, Iwo nikan lola ododo to si o


Olorun agbaye, mo f’ogo fun O ooo

Iwo loba Aseda, mo f′ogo fun O

Erujeje Arugbo Ojo, Agba lailai on lo je

Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O

Olurapada wa, Ododo to n tan ′mole

Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O

Oba t’aa bi, sugbon ti a ko da

Iwo loba Aseda, mo f′ogo fun O

Ilekun to ti mo iku, Kokoro si iye ayeraye

Iwo loba Aseda, mo f′ogo fun O

You are the Might above all mights

Angels count Your glory, incomparable

Shining in beauty from heaven to heaven, Creator of eternal things

You are the first, before the heavenly angels

You bigger than searchable

Glorious and stylishly working all glory

Glory Oh Glory (Ogo ogo)

Unquestionable Great King, be Thou glorified Daddy

Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O

Awon angeli juba Re, lojoojo o lorun

Iwo loba Aseda, mo f′ogo fun O

Embodiment of wisdom and power You are

Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O

Agbaagba lorun juba Re, won fi′ba yi O ka Baba

Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O

Worker of numerous wonders, worshipped in trembling

Iwo loba Aseda, mo f′ogo fun O

Gbogbo aye mi ni mo fi juba Re, gba ogo lori mi o Baba

Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O

You are the King Creator, be Thou glorified

Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O

Ola ododo lo to si ′Wo nikan nikan o

Iwo loba Aseda, mo f′ogo fun O

Iba Re Olorun o, Oba ayeraye e

Kabiyesi Re o, Iwo nikan lola ododo to si

Mo wa juba Re o, Iwo nikan lola ododo to si o


Note: Please support wikilyrics by Sharing or dropping a comment here. Also, You can submit song lyrics, poem or anthem here and reach thousands of Audience!
VIEW:  KUMITE Lyrics Salmo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *